Pan African Digest
Femi African Report Podcast
Yoruba proverb Audio #1
1
0:00
-0:41

Yoruba proverb Audio #1

1

Bí ẹ̀dá bá fẹ́ gba àwìn ẹ̀bà, ni wọ́n máa ńṣe ojú àánú; tí wọ́n bá yó tán, wọ́n á di ọkọ olúwa wọn / People present a facade of humility when seeking favour, but easily lord it over their benefactors, once satisfied. [Be perceptive; you never know who anyone truly is.]

Discussion about this episode

User's avatar